Greetings in Contexts

Vocabulary

Useful Vocabulary

ìgbeyàwó wedding
ìkómọjáde/Ìsọmọlórúkọ child naming ceremony
ìgbéga promotion
ìkẹ́kọgboyè graduation
ìfinijoyè putting someone in a position, e.g. Kings and Chiefs
ayẹyẹ celebration
àdúrà prayer
súre to bless
àṣeyọrí success
fi ojú s'ọ́nà to be expectant
ojúlùmọ̀ well-wishers
ná owó àti ara spent their time and self (by serving)
wáyé come to be/take place
èso fruit
ewu danger

 

 

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by kdthomp3. All Rights Reserved.