Àwọn Iṣẹ́ (Jobs)

Sísọ̀rọ̀ nípa iṣé

olanipekun

When talking about a profession, we must identify the name of the profession (Kíni orúkọ iṣẹ́ yìí?) We also talk about what people in this job do- (Bii àpẹrẹ: Kíni àwọn olukọ́ maa ń ṣẹ?) We can also talk about the significance (Kini pàtàkí iṣẹ́ yìí?), dangers (Ṣé iṣẹ́ yìí ni ewu?), and tools associated with the profession (Kini wọn maa n lo?)
Iṣẹ́ Ọlọpa
      Lóòni, ẹ jẹ́ kà sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ ọlọpa. Àwọn Ọlọ́pàá máa ń dáàbòbò awọn ará ilú. Iṣẹ́ wọn ni lati mú àwọn ọ̀daràn, olè, ọlọ́ṣà, ọ̀lẹ àti oníjàgídíjà kúrò láàrin ìlú. Wọ́n máa ní ìbọn ati ọ̀pá. Iṣẹ́ wọn ṣọ̀rọ nítori ewu àti ìjàǹbá ninu iṣẹ nàá. A ní Ọlọ́pàá inú atí Ọlọ́pàá ìta?

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by olanipekun. All Rights Reserved.