Describing with Colors

Short Reading

Ní ilẹ̀ Yorùbá, àwọ̀ aṣọ máa ń fi ohun tí ó wà ní ọkàn ènìyàn hàn; tí inú ènìyàn bá dùn tàbí tí ó bá bàjẹ́. Ní òde ìnáwó tàbí àjọyọ̀, àwọ̀ tí ó tàn ni ó tọ̀nà láti wọ̀. Ní ibi tí ìjàmbá tàbí nǹkan bá ti ṣẹlẹ̀, àwọ̀ tí kò tàn ni ó tọ̀nà láti wọ̀. Fún àpẹẹrẹ:

Òkú ọ̀fọ̀ – dúdú/àwọ̀ tí kò tàn

Òkú ọlọ́mọ – àwọ̀ tí ó tàn

Inú dídùn – àwọ̀ tí ó tàn

Inú bíbájẹ́ – àwọ̀ tí kò tàn

 

Reading Test

Read the passage above carefully and answer the following questions:

 

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by kdthomp3. All Rights Reserved.