Describing People

Useful Vocabulary: Relationship

ìyá/màma mother
bàbá father
ẹ̀gbọ́n elder sibling
àbúrò younger sibling
ẹ̀gbọ́n màmá/bàbá parents' elder sibling
àbúrò màmá/bàbá parents' younger sibling
ọ̀rẹ́ mí tímọ́tímọ́ bestfriend
ọ̀gá boss
ọmọ iṣẹ́ apprentice
òníbàárà customer

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by kdthomp3. All Rights Reserved.