Greetings in Contexts

Commiserating

Oríṣiríṣi ìṣẹ̀lẹ̀ ibi tàbí àjálú ibi ni ó lè ṣẹlẹ̀: ikú (ọ̀fọ̀), ìjàmbá ọkọ̀, ìjàmbá inú ilẹ́, àìsàn, ìdáni dúró ni ibi iṣẹ́, abbl. Tí ó bá ṣẹlẹ̀, a gbọ́dọ̀ bá àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ kẹ́dùn.

Ìkíni àti àwọn ọ̀rọ̀ tí a lẹ̀ lò

(Ẹ) pẹ̀lẹ́ (Generally)

(Ẹ) má barajẹ́ (for those grieving)

(Ẹ) má farálẹ̀ (someone ill to recover quickly)

(Ẹ) tọ́jú ara yín o (take care of you)

(Ẹ) kóra gírí (pull yourself together)

(Ẹ) mú ọkàn le (be strong)

(Ẹ) kò ní rí irú rẹ̀ mọ́ (You won’t experience such again)

To respond to such visit, you tell the person

A kò ní fi irú rẹ̀ sán fún ara wa (We won’t have reasons to repay each other with such visit).

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by kdthomp3. All Rights Reserved.