Describing People

Fairọọsi Korona

michael

Lesson Objective

At the end of this lesson, students will be able to talk about symptoms and ways of combating coronavirus.

Lesson

Stage 1: Knowing COVID-19 symptoms.
– Àwọn àmì kòrónà nìwònyí: ikọ (=cough), ìnira láti mi (=difficulty in breathing), àti ibà (=fever)
– Study the images below (àwòrán kíni, àwòrán kejì, àwòrán kẹta) and identify COVID-19 symptoms by completing the sentences that follow:

 

 

 

 

Dáhùn ìbéèrè ìsàlẹ̀ yìí:

    1. àwòrán kíni jẹ́ àmì ____
    2. àwòrán kejì jẹ́ àmì ____
    3. àwòrán kẹta jẹ́ àmì ____
Stage 2: Preventing COVID-19

– Below are steps for preventing the spread of the virus:

– jìnà sí ibi tí àwọn ènìyàn ti kó jọ pọ̀.

– yẹra fún ìpéjọpọ̀.

– Wọ ìbòjú láti dáàbò bo àwọn ènìyàn àti ara wa.

– bo ikọ́ wa tàbí sín nípa lílo ìgunpá wa.

– fọ ọwọ́ wa nígbà gbogbo dáradára pẹ̀lú ọṣẹ àti omi.

– nu àwọn ibi tí ọwọ́ ń kàn lóòrè-kóòrè pẹ̀lú kẹ́míkà apakòkòrò láti jẹ́ kí wọ́n wà láìléwu.

Stage 3: Study the images below and answer the question that follows:
A.                                                                B.                                                     C.

               

– Question: match the activity below with the right location (in the images above) by writing the appropriate letter in front of the sentence. Then, construct a sentence that contains both activity and the location. Sentence 1 has been done for you:

    1. yẹra fún àwọn ìpéjọpọ̀ – stay away from social clustering [B.]
      1. Mo yẹra fún àwọn ìpéjọpọ̀ ní ìta-gbangba (=outside).
    2. wọ ìbòjú – wear facemask
    3. ṣe àyẹ̀wò – get tested
    4. rí àmì – see symptoms
    5. bo ikọ́ – cover cough
    6. fọ ọwọ́ – wash hands
    7. gba àjẹsára – take vaccine
Stage 4: Scenario

Create a dialogue a doctor and a patient who shows signs of COVID-19. Conversation should involve symptoms and prevention measures.

    • Aláìsàn (patient):
    • Dókítà (doctor):

License

Icon for the Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License

Fairọọsi Korona Copyright © by michael is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License, except where otherwise noted.

Share This Book