Expressing Pain and Illness
Tobi Idowu
- To express pain, you can use the body parts + personal pronouns + generic verb, dùn (which is, pain).
- You can use body parts + personal pronouns + specific idiom to talk about a specific illness.
- Sometimes, you can also use particular illness + verbs (such as se, mú, gbé) + personal pronouns
Orí ń dùn mí
Ẹsẹ̀ ń dùn wọ́n
Ojú ń dùn é
Ọwọ́ ń dùn mí
- Ojú ń ta mí
Imú ń ro mí
Inú ń run mí
Ara ń ro mí
Àyà ń ta mí
- Òtútù ń mú mi
Ibà ń se mí
Òyì ń kọ́ mi
Ẹ̀fọ́rí ń ṣe mí
Èébì ń gbé mi
Ara ń só mí
Ikọ́ ń ṣe mí
Ise sise (role-playing)
Assume either of you is a doctor while the other is a patient. The doctor asks questions. The patient says what’s doing them, while the doctor offers a medical solution. Use these words as cues to talk (ẹ̀yìn, inú, ibà, ikọ́, àyà, ara, ojú).
Inú mi duń
Inú ń duń mí
Example:
Doctor: Kí ló ń ṣe ẹ́?
Patient: Orí ń fọ́ mi
Doctor: Pẹ̀lẹ́, lo asipírínì