Lẹ́tà Gbẹ̀fẹ̀

Tobi Idowu

Lẹ́tà jẹ́ ọ̀kan lára ọ̀nà tí a fi ń báni sọ̀rọ̀.

Lẹ́tà Gbẹ̀fẹ̀

 

A máa ń kọ lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀ sí àwọn tí ó bá sún mọ́ wa bí asọ.

Àpẹrẹ: Ìyá, Bàbá, òlólùfẹ́, àbúrò, ẹgbọ́n…

Ìgbésẹ̀ láti kọ lẹ́tà

  1. Àdírẹ́sì òǹkọ̀wé lẹ́tà lápa ọ̀tún òkè lẹ́tà
  2. Ọjọ́ (date)
  3. Ìbẹ̀rẹ̀ lẹ́tà (Màmá mi ọ̀wọ́n, Douglas mi tòótọ́)
  4. Ìkíni ìbẹ̀rẹ̀ lẹ́tà (Greetings)
  5. Kókó ọ̀rọ̀(Reason for writing)
  6. Ìkáàdí tàbí ìgúnlẹ̀ (Conclusion).
  7. Orúko òǹkòwé ní apá ọ̀tún ní ìpári lẹ́tà

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by Tobi Idowu. All Rights Reserved.