Describing People

Useful Vocabulary: Personality Traits

ìgboyà boldness
ojo coward
sùúrù patience
jàgídí jàgan stubborn
akínkanjú courageous
ìgbéraga pride
ìrẹ̀lẹ̀ humility
aláìgbọràn disobedient
òyàyà amusing
aláwàdà comedian/jester
onínúre kind-hearted
ọ̀lẹ lazy
òṣìṣẹ́ takuntakun hardworking
ìtẹ́lọ́rùn contentment
olówó wealthy
tálákà/akúṣẹ̀ẹ́ poor
le tough
dára good
ọlọ́gbọ́n wise
íwàpẹ̀lẹ́ meekness

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by kdthomp3. All Rights Reserved.