Describing People
Useful Vocabulary: Personality Traits
ìgboyà | boldness |
ojo | coward |
sùúrù | patience |
jàgídí jàgan | stubborn |
akínkanjú | courageous |
ìgbéraga | pride |
ìrẹ̀lẹ̀ | humility |
aláìgbọràn | disobedient |
òyàyà | amusing |
aláwàdà | comedian/jester |
onínúre | kind-hearted |
ọ̀lẹ | lazy |
òṣìṣẹ́ takuntakun | hardworking |
ìtẹ́lọ́rùn | contentment |
olówó | wealthy |
tálákà/akúṣẹ̀ẹ́ | poor |
le | tough |
dára | good |
ọlọ́gbọ́n | wise |
íwàpẹ̀lẹ́ | meekness |