Describing People
Fairọọsi Korona
michael
Lesson Objective
At the end of this lesson, students will be able to talk about symptoms and ways of combating coronavirus.
Lesson
Stage 1: Knowing COVID-19 symptoms.
– Àwọn àmì kòrónà nìwònyí: ikọ (=cough), ìnira láti mi (=difficulty in breathing), àti ibà (=fever)
– Study the images below (àwòrán kíni, àwòrán kejì, àwòrán kẹta) and identify COVID-19 symptoms by completing the sentences that follow:
Dáhùn ìbéèrè ìsàlẹ̀ yìí:
-
- àwòrán kíni jẹ́ àmì ____
- àwòrán kejì jẹ́ àmì ____
- àwòrán kẹta jẹ́ àmì ____
Stage 2: Preventing COVID-19
– Below are steps for preventing the spread of the virus:
– jìnà sí ibi tí àwọn ènìyàn ti kó jọ pọ̀.
– yẹra fún ìpéjọpọ̀.
– Wọ ìbòjú láti dáàbò bo àwọn ènìyàn àti ara wa.
– bo ikọ́ wa tàbí sín nípa lílo ìgunpá wa.
– fọ ọwọ́ wa nígbà gbogbo dáradára pẹ̀lú ọṣẹ àti omi.
– nu àwọn ibi tí ọwọ́ ń kàn lóòrè-kóòrè pẹ̀lú kẹ́míkà apakòkòrò láti jẹ́ kí wọ́n wà láìléwu.
Stage 3: Study the images below and answer the question that follows:
A. B. C.
– Question: match the activity below with the right location (in the images above) by writing the appropriate letter in front of the sentence. Then, construct a sentence that contains both activity and the location. Sentence 1 has been done for you:
-
- yẹra fún àwọn ìpéjọpọ̀ – stay away from social clustering [B.]
- Mo yẹra fún àwọn ìpéjọpọ̀ ní ìta-gbangba (=outside).
- wọ ìbòjú – wear facemask
- ṣe àyẹ̀wò – get tested
- rí àmì – see symptoms
- bo ikọ́ – cover cough
- fọ ọwọ́ – wash hands
- gba àjẹsára – take vaccine
- yẹra fún àwọn ìpéjọpọ̀ – stay away from social clustering [B.]
Stage 4: Scenario
Create a dialogue a doctor and a patient who shows signs of COVID-19. Conversation should involve symptoms and prevention measures.
-
- Aláìsàn (patient):
- Dókítà (doctor):