Ìlera (Health)

Kíló ń ṣe ẹ́?

olanipekun

 

dókítà àtí ẹni ti ó wá ṣe àyèwo

 

To ask about the health status of someone, you ask:

  •     Kíló ń ṣe ẹ́?
  •    Bàwo lo ṣe ń ṣe yín?
  •    Bawo ni ara ẹ?

 

Answers could be:

  •     Ara mi ò yá
  •    Ara mi ti ya

General pain, signs and symptoms

Dùn-pain

 1. ẹsẹ̀ ń dùn mí
 2. eyín ń dùn wọn.
 3. ọ̀fun ń dún Ṣade

 

Specific pain to body parts

1 Orí/ fọ́ Ori ń fọ́ mi
2 Inú/run Ṣe inu ń run ẹ?
3 Ara/ro Ara ń ro Kíkẹ́

 

 

Òtútù ń mú mí

Òyì ń kọ́ mí

Ara mi n gbóná

License

Materials for Yoruba Learners Copyright © by olanipekun. All Rights Reserved.