Ìlera (Health)
Kíló ń ṣe ẹ́?
olanipekun
To ask about the health status of someone, you ask:
-
- Kíló ń ṣe ẹ́?
- Bàwo lo ṣe ń ṣe yín?
- Bawo ni ara ẹ?
Answers could be:
-
- Ara mi ò yá
- Ara mi ti ya
General pain, signs and symptoms
Dùn-pain
- ẹsẹ̀ ń dùn mí
- eyín ń dùn wọn.
- ọ̀fun ń dún Ṣade
Specific pain to body parts
1 | Orí/ fọ́ | Ori ń fọ́ mi |
2 | Inú/run | Ṣe inu ń run ẹ? |
3 | Ara/ro | Ara ń ro Kíkẹ́ |
Òtútù ń mú mí
Òyì ń kọ́ mí
Ara mi n gbóná