Describing People
Useful Vocabulary: Personality Traits
| ìgboyà | boldness |
| ojo | coward |
| sùúrù | patience |
| jàgídí jàgan | stubborn |
| akínkanjú | courageous |
| ìgbéraga | pride |
| ìrẹ̀lẹ̀ | humility |
| aláìgbọràn | disobedient |
| òyàyà | amusing |
| aláwàdà | comedian/jester |
| onínúre | kind-hearted |
| ọ̀lẹ | lazy |
| òṣìṣẹ́ takuntakun | hardworking |
| ìtẹ́lọ́rùn | contentment |
| olówó | wealthy |
| tálákà/akúṣẹ̀ẹ́ | poor |
| le | tough |
| dára | good |
| ọlọ́gbọ́n | wise |
| íwàpẹ̀lẹ́ | meekness |