Describing People
Useful Vocabulary: Relationship
ìyá/màma | mother |
bàbá | father |
ẹ̀gbọ́n | elder sibling |
àbúrò | younger sibling |
ẹ̀gbọ́n màmá/bàbá | parents' elder sibling |
àbúrò màmá/bàbá | parents' younger sibling |
ọ̀rẹ́ mí tímọ́tímọ́ | bestfriend |
ọ̀gá | boss |
ọmọ iṣẹ́ | apprentice |
òníbàárà | customer |