Greetings in Contexts
Vocabulary
Useful Vocabulary
ìgbeyàwó | wedding |
ìkómọjáde/Ìsọmọlórúkọ | child naming ceremony |
ìgbéga | promotion |
ìkẹ́kọgboyè | graduation |
ìfinijoyè | putting someone in a position, e.g. Kings and Chiefs |
ayẹyẹ | celebration |
àdúrà | prayer |
súre | to bless |
àṣeyọrí | success |
fi ojú s'ọ́nà | to be expectant |
ojúlùmọ̀ | well-wishers |
ná owó àti ara | spent their time and self (by serving) |
wáyé | come to be/take place |
èso | fruit |
ewu | danger |