Lẹ́tà Gbẹ̀fẹ̀
Tobi Idowu
Lẹ́tà jẹ́ ọ̀kan lára ọ̀nà tí a fi ń báni sọ̀rọ̀.
Lẹ́tà Gbẹ̀fẹ̀
A máa ń kọ lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀ sí àwọn tí ó bá sún mọ́ wa bí asọ.
Àpẹrẹ: Ìyá, Bàbá, òlólùfẹ́, àbúrò, ẹgbọ́n…
Ìgbésẹ̀ láti kọ lẹ́tà
- Àdírẹ́sì òǹkọ̀wé lẹ́tà lápa ọ̀tún òkè lẹ́tà
- Ọjọ́ (date)
- Ìbẹ̀rẹ̀ lẹ́tà (Màmá mi ọ̀wọ́n, Douglas mi tòótọ́)
- Ìkíni ìbẹ̀rẹ̀ lẹ́tà (Greetings)
- Kókó ọ̀rọ̀(Reason for writing)
- Ìkáàdí tàbí ìgúnlẹ̀ (Conclusion).
- Orúko òǹkòwé ní apá ọ̀tún ní ìpári lẹ́tà