Yoruba

Asking about/Describing a person

 Describing People

Objective: The objective of this Yoruba language learning activity is to enable learners to ask and describe information about a person in Yoruba, such as name, age, nationality, appearance, and occupation.

Instruction:

1. Review relevant Yoruba vocabulary related to describing people, such as ga(tall), sanra(fat), tinrin(thin), etc.

2. Show pictures of people displaying different physical features and attributes. Ask learners to identify the characteristics in Yoruba. Repeat this process with multiple flashcards to reinforce vocabulary and sentence construction.

3. Role-Play Activity

Titi met someone who said she knows Toyin, but Toyin does not remember this person and is trying to get as much as information from Titi as possible about her. Start a conversation under this scenario.

Titi: Mo pade enikan lana ti ó sọ pé òun mọ̀ ẹ́.

Toyin: Looto? Ki ni oruko rẹ̀?

Titi: Ó so pe òun jẹ́ Dami.

Toyin: Hmm! Mi ò ranti ẹnikẹ́ni t’ó ń jẹ́ Dami.

Titi: Ó sọ pé, bí mo bá ti sọ Dami, o máa ránti òun.

Toyin: Ọmọ ìlú ibo ni?

Titi: Mo ro pe ọmọ ilu Saina ni, ṣugbon ó n gbé ni Amerika nisisiyi.

Toyin: Láti igba wo l’ó ti n gbé ni Amerika?

Titi: Ó sọ pé ọdun meji sẹhìn.

Toyin: Ki l’ó n ṣe nisisiyi ni ilú Amerika?

Titi: Akekoo ni ní Yunifasiti ti Wisconsin-Madison. Lítírẹṣọ̀ ati àṣà ilẹ̀ Afitika ni ó n kọ.

Toyin: Síbẹ̀síbẹ̀, mi ò ránti ọmọ ilu Saina ti orukọ rẹ̀ n jẹ́ Dami. Ṣé o lè sapejuwe rẹ̀ fún mi?

Titi: Ó ga die. Kò sanra rárá. Kò sí tininrin.  Ó pupa. Ó ni irun dudu. Ẹyin ojú rẹ̀ dudu, Ó lọ́yaya gan an ni.

Toyin: Ọmọ ọdún melọ̀ọ́ ni o rò pé o máa jẹ́?

Titi: N kò mọ. Ó dabi ẹni pé ọmọ bí i odún merindinlogbọ̀n ni.

Toyin: Kò dagbà púpọ̀. Sé o mọ̀ boya ó ni ẹbí nibi?

Titi: Rara o. N kọ̀ mọ̀.

Toyin: Ó dàbí ẹni pé mo ti rántí ẹni tí o n soro nípa. Mo pàdé rẹ̀ ni yunifásítì ní oṣu ti o kojá.  O yà mi lẹ́nu pé ó si rántí mi.

 

4. The mentor provides feedback and corrections as needed to reinforce learning. The learner records the dialogue for future review.

 

License

Icon for the Creative Commons Attribution-NonCommercial-ShareAlike 4.0 International License

Resources for Self-Instructional Learners of Less Commonly Taught Languages Copyright © by University of Wisconsin-Madison Students in African 671 is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial-ShareAlike 4.0 International License, except where otherwise noted.