Yoruba
Gapped Text Exercise (by Ajara Jagne)
Overview
For this gapped text exercise, I chose part of a popular Yoruba song from the OGD All Stars Jamz album titled “Aiye Le.” It is a song that speaks about the hardships of life and how only God can help us through. The first section has the blanks, and the second section has the answers to the blanks. Here is the link to the original lyrics and song: https://www.shazam.com/en-us/song/199948240/aiye-le-choral.
Gapped Text
Aiye le
Aiye — —, oro — yi a
Oto — sun mi
Aiye le
Aiye ma le, — — — —
Oto ju sun mi
—- ti mo fe
Ohun ti mo —
— — ni to le se fun mi
Af’ olorun —
Ohun ti — fe
Ohun — mo bere
Ko se — to le — fun mi
Af’ — oba
Ohun ti mo fe
— ti mo —-
Ko se ni to le se fun mi
Af’ olorun oba
Original Text
Aiye le
Aiye ma le, oro aiye yi a
Oto ju sun mi
Aiye le
Aiye ma le, oro aiye yi a
Oto ju sun mi
Ohun ti mo fe
Ohun ti mo bere
Ko se ni to le se fun mi
Af’ olorun oba
Ohun ti mo fe
Ohun ti mo bere
Ko se ni to le se fun mi
Af’ olorun oba
Ohun ti mo fe
Ohun ti mo bere
Ko se ni to le se fun mi
Af’ olorun oba